1 Kíróníkà 3:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ọmọ Ṣékáníà:Ṣémáíà àti àwọn ọmọ Rẹ̀:Hátúsì, Ígéálì, Báríà, Néáríà àti Ṣáfátì, mẹ́fà ni gbogbo wọn.

1 Kíróníkà 3

1 Kíróníkà 3:16-24