1 Kíróníkà 29:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹgbẹ̀rún mẹ́ta (3,000) talẹ́ntì wúrà (wúrà ti ofírì) àti ẹgbẹ̀rin méje tálẹ́ntì fàdákà tí a yọ̀rọ̀ kúrò, fún bíbo àwọn ògiri ilé náà.

1 Kíróníkà 29

1 Kíróníkà 29:1-14