1 Kíróníkà 29:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti fún ọmọ mi Sólómónì ní ìfọkànsìn tòótọ́ láti pa àṣẹ rẹ mọ́ àwọn ohun tí ó nílò àti òfin àti láti ṣe ohun gbogbo láti kọ́ ààfin bí ti ọba fún èyí tí mo ti pèsè.”

1 Kíróníkà 29

1 Kíróníkà 29:9-25