1 Kíróníkà 29:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwa jẹ́ àjèjì àti àlejò ní ojú rẹ gẹ́gẹ́ bí baba ńlá a wa, àwọn ọjọ́ wa lórí ilẹ̀ ayé rí bí òjìji láìsí ìrètí.

1 Kíróníkà 29

1 Kíróníkà 29:6-20