1 Kíróníkà 28:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ninú gbogbo àwọn ọmọ mi pẹ̀lú Olúwa ti fún mi ní púpọ̀, ó ti yan ọmọ mi Sólómónì láti jòkó lórí ìtẹ́ ìjọba ti Olúwa lóri Isírẹ́lì.

1 Kíróníkà 28

1 Kíróníkà 28:1-12