1 Kíróníkà 28:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó yàn ìwọ̀n wúrà fún gbogbo ohun èlò wúrà tí a ó lò níbi orísìí ìsìn, àti ìwọ̀n fàdákà fún gbogbo ohun èlò fàdákà tí a ó lò fún oríṣìí ìsìn:

1 Kíróníkà 28

1 Kíróníkà 28:11-15