1 Kíróníkà 27:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Alákòóso fún ìpín àwọn ọmọ-ogun fún oṣù kejì jẹ́ Dódáì ará Áhóhì; Míkílótì jẹ́ olórí ìpín tirẹ̀. Ọkùnrin ẹgbàá ni ó wà ní ìpín tirẹ̀. (24,000).

1 Kíróníkà 27

1 Kíróníkà 27:1-6