1 Kíróníkà 27:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bálì Hánánì ará Gédérì wà ní ìdi Ólífì àti àwọn igi Ṣíkámórè ní apá ìhà ìwọ̀ oòrùn àwọn ní ẹ̀ṣẹ̀ pẹ̀tẹ́lẹ̀.Jóáṣì wà ní ìdí fífún ni ní òróró Ólífì.

1 Kíróníkà 27

1 Kíróníkà 27:24-29