1 Kíróníkà 27:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ti alákòóso lórí ìpín kìn-ín-ni fún oṣù kìn-ín-ní jẹ́ Jáṣóbéámù ọmọ Ṣábídiélì àwọn ọkùnrin ẹgbẹ̀rún mẹ́rin ólé ẹgbàá mẹ́rin ní ó wà ní abẹ́ (24,000) ìpín tirẹ̀.

1 Kíróníkà 27

1 Kíróníkà 27:1-5