1 Kíróníkà 27:17-21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

17. lórí Léfì: Háṣábíà ọmọ Kémúélì;lori Árónì: Ṣádókù;

18. lórí Júdà: Élíhù arákùnrin Dáfídì;lóri Ísákárì: Ómírì ọmọ Míkáélì;

19. lórí Ṣébúlúnì: Íṣímáíà ọmọ Óbádáyà;lori Náfitalì: Jérímótì ọmọ Áṣíríélì;

20. lórí àwọn ará Éfíráímù: Hòṣéà ọmọ Áṣásíà;lorí ààbọ̀ ẹ̀yà Mánásè: Jóélì ọmọ Pedáyà;

21. lorí ààbọ̀ ẹ̀yà Mánásè ní Gílíádì: Ìdó ọmọ Ṣékáráyà;lórí Bẹ́ńjámínì: Jásíélì ọmọ Ábínérì;

1 Kíróníkà 27