1 Kíróníkà 26:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo wọ̀nyí ní ìran ọmọ Obedi Édómù; àwọn àti ọmọkùnrin àti ìbátan wọn jẹ́ alágbára ọkùnrin pẹ̀lú ipá láti ṣe ìsìn náà. Àtẹ̀lé Obedi Édómù méjìlélọ́gọ́ta (62) ni gbogbo Rẹ̀.

1 Kíróníkà 26

1 Kíróníkà 26:5-11