1 Kíróníkà 26:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọmọ Rẹ̀ Ṣémáíà ní àwọn ọmọkùnrin pẹ̀lú tí wọ́n jẹ́ olórí ní ìdílé bàbá a wọn nítorí wọ́n jẹ́ ọkùnrin tó lágbára.

1 Kíróníkà 26

1 Kíróníkà 26:5-16