Gbogbo àwọn ọkùnrin yìí ni wọ́n wà lábẹ́ ìbojútó àwọn bàba wọn fún ohun èlò orin ilé Olúwa, pẹ̀lú Kínbálì, Písálítérì àti dùùrù, fún Ìsìn ilé Olúwa. Ásáfù, Jédútúnì, ọba.