1 Kíróníkà 23:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Élíásérì sì kú pẹ̀lú Àìní àwọn ọmọkùnrin: Ó ní ọmọbìnrin nìkan. Àwọn ọmọ ẹ̀gbọ́n, àwọn ọmọ Kísì, sì fẹ́ wọn.

1 Kíróníkà 23

1 Kíróníkà 23:19-28