1 Kíróníkà 22:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ sì ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn oníṣẹ́ ènìyàn: àwọn gbẹ́nàgbẹ́nà, àti àwọn oníṣọ̀nà òkúta àti àwọn agbẹ́-òkúta, àti gẹ́gẹ́ bí onírúurú ọlọ́gbọ́n ènìyàn ní gbogbo onírúurú iṣẹ́.

1 Kíróníkà 22

1 Kíróníkà 22:7-19