1 Kíróníkà 22:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí Olúwa kí ó fún ọ ni ọgbọ́n àti òye nígbà tí ó bá fi ọ́ se aláṣẹ lórí Ísírẹ́lì, Bẹ́ẹ̀ ni kí ìwọ kí ó lè pa òfin Olúwa Ọlọ́run mọ́.

1 Kíróníkà 22

1 Kíróníkà 22:8-19