1 Kíróníkà 22:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun ni ẹni náà tí yóò kọ́ ilé fún orúkọ mi. Yóò sì jẹ́ ọmọ mi, èmi yóò sì jẹ́ baba Rẹ̀ èmi yóò sì fi ìdi ìtẹ́ ìjọba Rẹ̀ múlẹ̀ lórí Ísírẹ́lì láéláé.’

1 Kíróníkà 22

1 Kíróníkà 22:9-17