1 Kíróníkà 20:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ̀nyí ni ìran ọmọ Ráfà ní Gátì, wọ́n sì subú sí ọwọ́ Dáfídì àti àwọn ọkùnrin Rẹ̀.

1 Kíróníkà 20

1 Kíróníkà 20:1-8