1 Kíróníkà 20:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú ogun mìíràn pẹ̀lú àwọn ará Fílístínì, Élíhánánì ọmọ Jáírè pa Láhímì arákùnrin Gòláyátì ará àti, Gátì ẹni ti ó ní ọ̀kọ̀ kan tí ó dàbí ọ̀pá ahunsọ.

1 Kíróníkà 20

1 Kíróníkà 20:2-8