1 Kíróníkà 2:53 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti ìdílé Kíríátì-Jéárímù: àti àwọn ara Ítírì, àti àwọn ará Pútì, àti àwọn ará Ṣúmátì àti àwọn ará Mísíhí-ráì: láti ọ̀dọ̀ wọn ni àwọn ọmọ ará Sórátì àti àwọn ará Ésítaólì ti wá.

1 Kíróníkà 2

1 Kíróníkà 2:44-55