1 Kíróníkà 2:30-34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

30. Àwọn ọmọ NádábùṢélédì àti Ápáímù. Ṣélédì sì kú láìsí ọmọ.

31. Àwọn ọmọ Ápáímù:Isì, ẹnití ó jẹ́ baba fún Ṣésánì.Ṣésánì sì jẹ́ baba fún Áhíláì.

32. Àwọn ọmọ Jádà, arákùnrin Ṣámáì:Jétérì àti Jónátanì. Jétérì sì kú láìní ọmọ.

33. Àwọn ọmọ Jónátanì:Pélétì àti Ṣásà.Àwọn wọ̀nyí ni ọmọ Jéráhímẹ́lì.

34. Ṣésánì kò sì ní ọmọkùnrin àwọn ọmọbìnrin nìkan ni ó ní.Ó sì ní ìránṣẹ́ ará Éjíbítì tí orúkọ Rẹ̀ ń jẹ́ Járíhà.

1 Kíróníkà 2