1 Kíróníkà 2:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣégúbù sì jẹ́ bàbá Jáírì, ẹni tí ó jẹ́ olùdarí ìlú mẹ́talélógún ní ilẹ̀ Gílíádì.

1 Kíróníkà 2

1 Kíróníkà 2:14-27