1 Kíróníkà 19:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n wọ́n sálọ kúrò níwájú Ísírẹ́lì, Dáfídì sì pa ẹgbẹ̀rún méje agun-kẹ̀kẹ́ wọn àti ẹgbàá mẹ́rin ọmọ-ogun ẹlẹ́sẹ̀. Ó pa Ṣófákì alákóṣo ọmọ ogun wọn pẹ̀lú.

1 Kíróníkà 19

1 Kíróníkà 19:14-19