1 Kíróníkà 18:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti Tébà àti Kúnì, ìlú tí ó jẹ́ ti Hádádéṣérì, Dáfídì mú ọ̀pọ̀ tánganran tí Ṣólómónì lò láti fi ṣe òkun tan-gan-ran, àwọn òpó àti orísìí ohun èlò tan-gan-ran.

1 Kíróníkà 18

1 Kíróníkà 18:1-13