1 Kíróníkà 18:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbá ti àwọn ará Áráméà nì ti Dámásíkù wá láti ran Hadadésérì ọba Ṣóbà lọ́wọ́, Dáfídì lu ẹgbàá méjì wọn bọ lẹ̀.

1 Kíróníkà 18

1 Kíróníkà 18:1-7