1 Kíróníkà 18:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì borí àwọn ará Móábù, wọ́n sì di ọmọ-ẹ̀yìn Rẹ̀, wọ́n sì mú owó òde wá.

1 Kíróníkà 18

1 Kíróníkà 18:1-3