1 Kíróníkà 17:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nisinsìn yìí, Olúwa, Jẹ́ kí ìlérí tí ìwọ ti se fún ìransẹ́ rẹ àti ilé Rẹ̀ di fífi ìdí múlẹ̀ títí láé. Ṣe gẹ́gẹ́ bí o ti se ìlérí.

1 Kíróníkà 17

1 Kíróníkà 17:20-24