1 Kíróníkà 16:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olùbùkún ni Olúwa, Ọlọ́run Ísírẹ́lì,láé àti láéláé.Lẹ́yìn náà gbogbo àwọn ènìyàn wí pé “Àmín” wọ́n sì Yin Olúwa.

1 Kíróníkà 16

1 Kíróníkà 16:34-38