1 Kíróníkà 16:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni igi ti ọ̀dàn yóò kọrin,Wọn yóò kọrin fún ayọ̀ níwájú Olúwa, Nítorí tí ó wá láti sèdájọ́ ayé.

1 Kíróníkà 16

1 Kíróníkà 16:28-42