1 Kíróníkà 15:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì kó gbogbo àwon ọmọ Ísírélì jọ ní Jérúsálẹ́mù láti gbé àpótí ẹ̀rí Olúwa wá sí ibi tí ó ti pèṣè sílẹ̀ fún un.

1 Kíróníkà 15

1 Kíróníkà 15:1-12