1 Kíróníkà 15:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣébéáníá, Jóṣáfátì, Nétanélì, Ámásáyì, Ṣekaríyà, Beniáyà àti Élíásérì ní àwọn àlùfáà, ti o ń fún ìpè níwájú àpótí ẹ̀rí Ọlọ́run. Obedi-Édómù àti Jéhíyà ni ó sì gbọdọ̀ jẹ́ olùsọ́nà fún àpótí ẹ̀rí.

1 Kíróníkà 15

1 Kíróníkà 15:20-29