1 Kíróníkà 15:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

àti pẹ̀lú wọn àwọn arákùnrin wọn tí a yàn bí olùrànlọ́wọ́ wọn: Ṣekaríyà, Jásíélì; Ṣémírámótì, Jéhíélì, Únì, Élíféléhù, Míkíméíà, àti àwọn asọ́bodè Obedi-Edomu àti Jélíélì.

1 Kíróníkà 15

1 Kíróníkà 15:9-26