1 Kíróníkà 15:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí tí ẹ̀yin ọmọ Léfì kò gbe gòkè wá ní ìgbà àkọ́kọ́ ti Olúwa Ọlọ́run wa ya ìbínú Rẹ̀ lù wá. Àwa kò sì ṣe ìwádìí lọ́wọ́ Rẹ̀ nípa bí a ti ń ṣe é gẹ́gẹ́ bí ọ́nà tí a là sílẹ̀.

1 Kíróníkà 15

1 Kíróníkà 15:6-18