1 Kíróníkà 14:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ará Fílístínì sì ti fi àwọn òrìṣà wọn sílẹ̀ níbẹ̀. Dáfídì sì paá láṣẹ láti jó wọn nínú iná.

1 Kíróníkà 14

1 Kíróníkà 14:10-14