1 Kíróníkà 13:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì àti gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pẹ̀lú Rẹ̀ lọ sí Báláhì ti Júdà (Kiriati-Jéárímù) láti gbé àpótí ẹ̀rí Ọlọ́run Olúwa tí a fi orúkọ Rẹ̀ pè, tí ó jókòó láàrin kérúbù-gòkè wá.

1 Kíróníkà 13

1 Kíróníkà 13:1-10