1 Kíróníkà 13:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìbínú Olúwa, sì ru sí Úsà, ó sì lùú bolẹ̀ nítorí o ti fi ọwọ́ Rẹ̀ lórí Àpótí ẹ̀rí. Bẹ́ẹ̀ ni ó sì kú síbẹ̀ níwájú Ọlọ́run.

1 Kíróníkà 13

1 Kíróníkà 13:9-14