1 Kíróníkà 12:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lati ìlà òrùn Jódánì, ọkùnrin Réubénì, Gádì, àti ìdájì ẹ̀yà Mánásè, dìmọ́ra pẹ̀lú gbogbo onírúurú ohun èlò ìjà ọ̀kẹ́ mẹ́fà (120,000).

1 Kíróníkà 12

1 Kíróníkà 12:28-40