1 Kíróníkà 12:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ọkùnrin Náfítalì, ẹgbẹ̀rún (1,000) ìjòyè àpapọ̀ pẹ̀lú ẹgbàá méjìdínlógún (36,000) Ọkùnrin tí wọ́n gbé àṣà àti ọ̀kọ̀ wọn.

1 Kíróníkà 12

1 Kíróníkà 12:24-40