1 Kíróníkà 12:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Áhíésérì Olórí wọn àti Jóáṣì àwọn ọmọ Ṣémà ará Gíbéà: Jésíélì àti pélétì ọmọ Ásímáfétì, Bérákà, Jéhù ará Ánátótì.

1 Kíróníkà 12

1 Kíróníkà 12:1-8