1 Kíróníkà 12:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì ran Dáfídì lọwọ lórí ẹgbẹ́ ogun náà, nítorí gbogbo wọn ni akọni ènìyàn àwọn sì tún ni olórí nínú àwọn ọmọogun Rẹ̀.

1 Kíróníkà 12

1 Kíróníkà 12:15-24