1 Kíróníkà 11:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì ti wí pé Ẹnikẹ́ni tí ó bá darí àti kọlu àwọn ará Jébúsì ni yóò di olórí balógun, Jóábù ọmọ Sérúíà lọ sókè lákòókọ́, bẹ́ẹ̀ ni ó sì gba olórí.

1 Kíróníkà 11

1 Kíróníkà 11:1-13