1 Kíróníkà 11:38-40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

38. Jóẹ́lì arákùnrin NátanìMíbárì ọmọ Hágárì,

39. Ṣélékì ará Ámónì,Náháráì ará Bérótì ẹni tí ó jẹ́ áru ìhámọ́ra Jóábù ọmọ Ṣérúyà.

40. Írà ará Ítírì,Gárébù ará Ítírì,

1 Kíróníkà 11