1 Kíróníkà 11:27-35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

27. Ṣámótù ará Hárórì,Hélésì ará Pélónì

28. Írà ọmọ Íkéṣì láti Tékóà,Ábíésérì láti Ánátótì,

29. Ṣíbékíà ará Húṣátì,láti ará Áhóhì

30. Máháráì ará Nétófà,Hélédì ọmọ Báánà ará Nétófà,

31. Ítaì ọmọ Ríbáì láti Gíbéà ní Bẹ́ńjámínì,Bẹ́náyà ará Pírátónì,

32. Húráì láti odò Gáṣì,Ábíélì ará Áríbátì,

33. Ásímáfétì ará BáhárúmùÉlíábà ará Ṣáíbónì

34. Àwọn ọmọ Háṣémù ará GísónìJónátanì ọmọ ṣágè ará Hárárì.

35. Áhíámù ọmọ sákárì ará Hárárì,Élífálì ọmọ Úrì

1 Kíróníkà 11