1 Kíróníkà 11:25-31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

25. Ó sì ní ọlá púpọ̀ ju àwọn ọgbọ̀n (30) lọ, ṣùgbọ́n a kò káà láàrin àwọn mẹ́tẹ̀ta. Dáfídì sì fi sí ìkáwọ́ àwọn ẹ̀sọ́.

26. Àwọn akọni ọkùnrin náà nìyí:Ásáhélì arákùnrin Jóábù,Élíhánánì ọmọ Dódò láti Bẹ́tílẹ́hẹ́mù,

27. Ṣámótù ará Hárórì,Hélésì ará Pélónì

28. Írà ọmọ Íkéṣì láti Tékóà,Ábíésérì láti Ánátótì,

29. Ṣíbékíà ará Húṣátì,láti ará Áhóhì

30. Máháráì ará Nétófà,Hélédì ọmọ Báánà ará Nétófà,

31. Ítaì ọmọ Ríbáì láti Gíbéà ní Bẹ́ńjámínì,Bẹ́náyà ará Pírátónì,

1 Kíróníkà 11