1 Kíróníkà 11:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ábíṣáì arákùnrin Jóábù ìjòyè àwọn mẹ́ta. Ó sì gbé ọ̀kọ̀ Rẹ̀ sókè lórí àwọn ọ̀dúnrún àwọn ènìyàn, àwọn ẹni tí ó pa, bẹ́ẹ̀ ni ó sì di olókìkí gẹ́gẹ́ bí àwọn mẹ́ta.

1 Kíróníkà 11

1 Kíróníkà 11:12-22