1 Kíróníkà 1:7-12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

7. Àwọn ọmọ Jáfánì:Èlíṣà, Tárísísì, Kítímù, àti Dódánímù.

8. Àwọn ọmọ Ámù:Kúṣì, Ṣébà, Mísíráímù, Pútì, àti Kénánì.

9. Àwọn ọmọ Kúṣì:Ṣébà Háfílà, Ṣébítà, Rámà, àti Ṣábítékà,Àwọn ọmọ Rámà:Ṣébà àti Dédánì.

10. Kúṣì ni baba Nímíródù:Ẹni tí ó dàgbà tí ó sì jẹ́ jagunjagun alágbára lórí ilẹ̀ ayé.

11. Mísíráímù ni babaLúdímù, Ánámímù, Léhábímù, Náfítúhímù,

12. Pátírísímù, Kásiliúhímù, (Láti ọ̀dọ̀ ẹni tí àwọn ará Fílístínì ti wá) àti Káfitórímù.

1 Kíróníkà 1