1 Kíróníkà 1:20-30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

20. Jókítanì sì jẹ́ Baba fúnHímódádì, Ṣéléfì, Hásárímáfétì, Jérà.

21. Hádórámì, Úsálì, àti Díkílà

22. Ébálì, Ábímáélì, Ṣébà.

23. Ófírì, Háfílà, àti Jóbábù. Gbogbo àwọn wọ̀nyí sì jẹ́ àwọn ọmọ Jókítanì.

24. Ṣémù, Árífákásádì, Sẹ́bà,

25. Ébérì, Pélégì. Réù,

26. Ṣérúgì, Náhórì, Térà:

27. Àti Ábúrámù (tí ń ṣe Ábúráhámù).

28. Àwọn ọmọ Ábúráhámù:Ísáákì àti Íṣímáẹ́lì.

29. Èyí ni àwọn ọmọ náà:Nébáíótì àkọ́bí Íṣímáẹ́lì: Kédárì, Ádíbélì, Míbísámù,

30. Míṣímà, Dúmà, Másà, Hádádì, Témà,

1 Kíróníkà 1