1 Kíróníkà 1:2-7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

2. Kénánì, Máháláléélì, Jérédì,

3. Hénókì, Mètúsẹ́là, Lámékì, Nóà.

4. Àwọn ọmọ Nóà,Ṣémù, Ámù àti Jáfétì.

5. Àwọn ọmọ Jáfétì:Gómérì, Mágógù, Mádà; Jáfánì, Túbálì, Méṣékì, Tírásì

6. Àwọn ọmọ Gómérì:Áṣíkénásì, Bífátì, Tógárímà.

7. Àwọn ọmọ Jáfánì:Èlíṣà, Tárísísì, Kítímù, àti Dódánímù.

1 Kíróníkà 1