1. Ádámù, Ṣétì, Énọ́sì,
2. Kénánì, Máháláléélì, Jérédì,
3. Hénókì, Mètúsẹ́là, Lámékì, Nóà.
4. Àwọn ọmọ Nóà,Ṣémù, Ámù àti Jáfétì.
5. Àwọn ọmọ Jáfétì:Gómérì, Mágógù, Mádà; Jáfánì, Túbálì, Méṣékì, Tírásì
6. Àwọn ọmọ Gómérì:Áṣíkénásì, Bífátì, Tógárímà.
7. Àwọn ọmọ Jáfánì:Èlíṣà, Tárísísì, Kítímù, àti Dódánímù.