1 Jòhánù 5:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

nítorí olúkúlùkù ẹni tí a bí nípa tí Ọlọ́run, ó ṣẹ́gun ayé: èyí sì ni ìṣẹ́gun tí ó ṣẹ́gun ayé, àní ìgbàgbọ́ wa.

1 Jòhánù 5

1 Jòhánù 5:2-11